Luku 23:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ekeji bá a wí, ó ní, “Ìwọ yìí, o kò bẹ̀rù Ọlọrun. Ìdájọ́ kan náà ni wọ́n dá fún un bíi tiwa.

Luku 23

Luku 23:32-52