Luku 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Pilatu bá bi í pé, “Ṣé ìwọ ni ọba àwọn Juu?”Ó dá a lóhùn pé, “O ti fi ẹnu ara rẹ wí i.”

Luku 23

Luku 23:1-5