Luku 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin dúró níbẹ̀, wọ́n ń tẹnu mọ́ ẹ̀sùn tí wọn fi kàn án.

Luku 23

Luku 23:4-19