Luku 22:66 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn àgbààgbà ati àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin péjọ, wọ́n fa Jesu lọ siwaju ìgbìmọ̀ wọn.

Luku 22

Luku 22:61-70