Luku 22:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tó bíi wakati kan, ọkunrin kan tún sọ pẹlu ìdánilójú pé, “Láìsí àní-àní ọkunrin yìí wà pẹlu Jesu, nítorí ará Galili ni.”

Luku 22

Luku 22:53-66