Luku 22:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu sọ pé, “Ẹ fi wọ́n sílẹ̀.” Ó bá fọwọ́ kan etí ẹrú náà, etí náà sì san.

Luku 22

Luku 22:50-57