Luku 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo sọ fun yín pé láti àkókò yìí lọ, n kò tún ní mu ninu èso àjàrà mọ́ títí ìgbà tí ìjọba Ọlọrun yóo fi dé.”

Luku 22

Luku 22:15-20