Luku 22:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni wọ́n bá lọ, wọ́n rí ohun gbogbo bí Jesu ti sọ fún wọn. Wọ́n sì tọ́jú gbogbo nǹkan fún àsè Ìrékọjá.

Luku 22

Luku 22:10-22