Luku 21:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Ṣugbọn irun orí yín kankan kò ní ṣègbé.

19. Ẹ óo gba ọkàn yín là nípa ìdúróṣinṣin yín.

20. “Nígbà tí ẹ bá rí i tí ogun yí ìlú Jerusalẹmu ká, kí ẹ mọ̀ pé àkókò tí yóo di ahoro súnmọ́ tòsí.

Luku 21