Luku 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn òbí yín, ati àwọn arakunrin yín, àwọn ẹbí yín, ati àwọn ọ̀rẹ́ yín, yóo kọ̀ yín, wọn yóo sì pa òmíràn ninu yín.

Luku 21

Luku 21:15-26