Luku 21:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún fi kún un fún wọn pé “Orílẹ̀-èdè kan yóo máa gbógun ti ekeji, bẹ́ẹ̀ ni ìjọba kan yóo sì máa gbógun ti ekeji.

Luku 21

Luku 21:6-11