Luku 21:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Bí Jesu ti gbé ojú sókè ó rí àwọn ọlọ́rọ̀ bí wọ́n ti ń dá owó ọrẹ wọn sinu àpótí ìṣúra.

2. Ó wá rí talaka opó kan, tí ó fi kọbọ meji sibẹ.

Luku 21