Luku 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń bá ara wọn sọ pé, “Bí a bá sọ pé, ‘Láti ọ̀run ni,’ yóo bi wá pé, ‘Kí ló dé tí ẹ kò fi gbà á gbọ́?’

Luku 20

Luku 20:1-9