Luku 2:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àjọ̀dún parí, tí wọn ń pada lọ sí ilé, ọmọde náà, Jesu, dúró ní Jerusalẹmu, ṣugbọn àwọn òbí rẹ̀ kò fura.

Luku 2

Luku 2:33-45