Luku 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan bá lọ kọ orúkọ wọn sílẹ̀, ẹnìkọ̀ọ̀kan lọ sí ìlú ara rẹ̀.

Luku 2

Luku 2:1-13