Luku 19:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ìbá ti dára tó lónìí, bí o bá mọ̀ lónìí ohun tí ó jẹ́ ọ̀nà alaafia rẹ! Ṣugbọn ó pamọ́ fún ọ.

Luku 19

Luku 19:41-45