Luku 19:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń wí pé,“Aláásìkí ni ẹni tí ó ń bọ̀ bí ọba ní orúkọ Oluwa.Alaafia ní ọ̀run! Ògo ní òkè ọ̀run!”

Luku 19

Luku 19:31-45