Luku 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fẹ́ rí Jesu kí ó mọ ẹni tí í ṣe. Ṣugbọn kò lè rí i nítorí ọ̀pọ̀ eniyan ati pé eniyan kúkúrú ni.

Luku 19

Luku 19:1-12