Luku 19:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà tí Jesu dé Jẹriko, ó ń la ìlú náà kọjá.

2. Ọkunrin kan wà tí ó ń jẹ́ Sakiu. Òun ni olórí agbowó-odè níbẹ̀. Ó sì lówó.

Luku 19