Luku 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá pa òwe yìí fún àwọn tí wọ́n gbójú lé ara wọn bí olódodo, tí wọn ń kẹ́gàn gbogbo àwọn eniyan yòókù.

Luku 18

Luku 18:1-15