Luku 18:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá dúró, ó ní kí wọ́n lọ fà á lọ́wọ́ wá sọ́dọ̀ òun. Nígbà tí ó dé, Jesu bi í pé,

Luku 18

Luku 18:31-43