Luku 18:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí a óo fi í lé àwọn tí kì í ṣe Juu lọ́wọ́. Wọn óo fi ṣe ẹ̀sín, wọn óo fi àbùkù kàn án, wọn óo tutọ́ sí i lára.

Luku 18

Luku 18:26-37