Luku 18:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru sọ fún un pé, “Wò ó ná! Àwa ti fi ohun gbogbo tí a ní sílẹ̀, a sì ti ń tẹ̀lé ọ.”

Luku 18

Luku 18:27-33