Luku 17:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo máa sọ pé, ‘Wò ó níhìn-ín’ tabi, ‘Wò ó lọ́hùn-ún’. Ẹ má lọ, ẹ má máa sáré tẹ̀lé wọn kiri.

Luku 17

Luku 17:16-30