Luku 16:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ipò òkú ni ó rí ara rẹ̀, tí ó ń joró. Ó wá rí Abrahamu ní òkèèrè pẹlu Lasaru ní ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Luku 16

Luku 16:22-25