Luku 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà bí ẹ kò bá ṣe é gbẹ́kẹ̀lé nípa nǹkan owó ti ayé yìí, ta ni yóo fi dúkìá tòótọ́ sí ìkáwọ́ yín?

Luku 16

Luku 16:1-20