Luku 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tabi, kí obinrin kan ní naira mẹ́wàá, bí ó ba sọ naira kan nù, ṣé kò ní tan iná, kí ó gbálẹ̀, kí ó fẹ̀sọ̀ wá a títí yóo fi rí i?

Luku 15

Luku 15:5-10