Luku 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ yìí bá sọ fún un pé, ‘Àbúrò rẹ dé, baba rẹ sì pa mààlúù tí ó sanra, ó se àsè nítorí tí àbúrò rẹ pada dé ní alaafia.’

Luku 15

Luku 15:21-29