Luku 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí àbúrò sọ fún baba rẹ̀ pé, ‘Baba, fún mi ní ogún tèmi tí ó tọ́ sí mi.’ Ni baba bá pín ogún fún àwọn ọmọ mejeeji.

Luku 15

Luku 15:4-13