Luku 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu ṣe akiyesi bí àwọn tí a pè sí ibi àsè ti ń yan ipò ọlá, ó wá pa òwe kan fún wọn. Ó ní,

Luku 14

Luku 14:1-17