Luku 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní Ọjọ́ Ìsinmi kan, Jesu lọ jẹun ní ilé ọ̀kan ninu àwọn olóyè láàrin àwọn Farisi. Wọ́n bá ń ṣọ́ ọ.

Luku 14

Luku 14:1-6