Luku 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo níláti kúrò kí n máa bá iṣẹ́ mi lọ lónìí, lọ́la ati lọ́tùn-unla, nítorí bí wolii kan yóo bá kú, ní Jerusalẹmu ni yóo ti kú.

Luku 13

Luku 13:32-35