Luku 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu rí i, ó pè é, ó sọ fún un pé, “Obinrin yìí, a wò ọ́ sàn kúrò ninu àìlera rẹ.”

Luku 13

Luku 13:5-16