Luku 12:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìgbà yìí, ẹni marun-un yóo wà ninu ilé kan, àwọn mẹta yóo lòdì sí àwọn meji; àwọn meji yóo lòdì sí àwọn mẹta.

Luku 12

Luku 12:49-54