Luku 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bẹ́ẹ̀ ni yóo rí fún ẹni tí ó to ìṣúra jọ fún ara rẹ̀, tí kò ní ọrọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọrun.”

Luku 12

Luku 12:16-24