Luku 11:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu jáde kúrò ninu ilé, àwọn amòfin ati àwọn Farisi takò ó, wọ́n ń bi í léèrè ọ̀rọ̀ pupọ,

Luku 11

Luku 11:45-54