Luku 11:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ tán, Farisi kan pè é pé kí ó wá jẹun ninu ilé rẹ̀. Ó bá wọlé, ó jókòó.

Luku 11

Luku 11:35-39