Luku 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ ọwọ́ Ọlọrun ni mo fi ń lé ẹ̀mí èṣù jáde, a jẹ́ pé ìjọba Ọlọrun ti dé ba yín.

Luku 11

Luku 11:11-24