Luku 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọmọ alaafia bá wà níbẹ̀, alaafia yín yóo máa wà níbẹ̀. Bí kò bá sí, alaafia yín yóo pada sọ́dọ̀ yín.

Luku 10

Luku 10:3-7