Luku 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má mú àpò owó lọ́wọ́, tabi àpò báárà. Ẹ má wọ bàtà. Bẹ́ẹ̀ ní kí ẹ má kí ẹnikẹ́ni ní ọ̀nà.

Luku 10

Luku 10:1-9