Luku 10:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bi í pé, “Kí ni ó wà ní àkọsílẹ̀ ninu òfin? Báwo ni o ti túmọ̀ rẹ̀?”

Luku 10

Luku 10:16-27