Luku 1:9-11 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Gẹ́gẹ́ bí àṣà àwọn alufaa, Sakaraya ni ìbò mú láti sun turari ninu iyàrá Tẹmpili Oluwa.

10. Gbogbo àwọn eniyan ń gbadura lóde ní àkókò tí ó ń sun turari.

11. Angẹli Oluwa kan bá yọ sí i, ó dúró ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀tún pẹpẹ turari.

Luku 1