Luku 1:79 BIBELI MIMỌ (BM)

láti tan ìmọ́lẹ̀ sí àwọn tí ó wà ní òkùnkùnati àwọn tí ó jókòó níbi òjìji ikú,láti fi ẹsẹ̀ wa lé ọ̀nà alaafia.”

Luku 1

Luku 1:73-80