Luku 1:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá bèèrè fún nǹkan ìkọ̀wé, ó kọ ọ́ pé, “Johanu ni orúkọ rẹ̀.” Ẹnu ya gbogbo eniyan.

Luku 1

Luku 1:55-71