Luku 1:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n ti kọ ìròyìn lẹ́sẹẹsẹ, nípa ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ láàrin wa;

2. àwọn tí nǹkan wọnyi ṣojú wọn, tí wọ́n sì sọ fún wa.

Luku 1