Lefitiku 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni bá súnmọ́ ibi pẹpẹ náà, ó pa ọ̀dọ́ mààlúù fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:1-9