Lefitiku 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose ati Aaroni bá wọ inú Àgọ́ Àjọ lọ. Nígbà tí wọ́n jáde, wọ́n súre fún àwọn eniyan náà, ògo OLUWA sì yọ sí gbogbo wọn.

Lefitiku 9

Lefitiku 9:20-24