Lefitiku 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó fa àgbò keji kalẹ̀, èyí tí í ṣe àgbò ìyàsímímọ́. Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ gbé ọwọ́ wọn lé e lórí.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:16-28