Lefitiku 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose gbé òróró ìyàsímímọ́, ó ta á sí gbogbo ara Àgọ́ náà ati ohun gbogbo tí ó wà ninu rẹ̀, ó sì yà wọ́n sí mímọ́.

Lefitiku 8

Lefitiku 8:6-14