Lefitiku 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹbọ ohun jíjẹ tí a yan ati gbogbo èyí tí a sè ninu apẹ tabi ninu àwo pẹrẹsẹ jẹ́ ti alufaa tí ó fi wọ́n rúbọ.

Lefitiku 7

Lefitiku 7:1-11